Hósíà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ̀,ẹni tó mú ọ jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá.Ìwọ̀ kì yóò sì mọ ọlọ́run mìíràn àfi èmikò sí olùgbàlà mìíràn lẹ́yìn èmi

Hósíà 13

Hósíà 13:1-6