Hósíà 10:11-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Éfúráímù jẹ́ ọmọ màlúù tí atí kọ́, to si fẹ́ràn láti máa pa ọkàlórí ọrun rẹ̀ tó lẹ́wà nièmi ó dí ẹru wúwo léÈmi yóò mú kí a gun Éfúráímù bí ẹṣinJúdà yóò tú ilẹ̀,Jákọ́bù yóò sì fọ́ ogúlùtu rẹ̀

12. Ẹ gbin òdòdó fún ara yínkí ẹ sì ká èso ìfẹ́ àìlópin,Ẹ tu ilẹ̀ yín tí a kòronítorí pé ó ti tó àsìkò láti wá Olúwa,títí tí yóò fi dé,tí yóò sì rọ òjò òdodo lé yín lórí.

13. Ṣùgbọ́n ẹ tí gbìn buburú ẹ si ka ibi,Ẹ ti jẹ èso èkénítorí ẹ tí gbẹ́kẹ̀ lé agbára yínàti àwọn ọ̀pọ̀ jagun jagun yín

Hósíà 10