Hábákúkù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìwọ tí ko orílẹ̀-èdè púpọ̀,àwọn ènìyàn tó kù yóò sì kó ọnítorí ìwọ tí ta ẹ̀jẹ̀ ènìyàn sílẹ̀; nítorí ẹ̀jẹ̀Ìwọ tí pa ilẹ̀ àti ìlú ńlá runàti gbogbo ènìyàn to ń gbé inú rẹ̀.

Hábákúkù 2

Hábákúkù 2:2-17