Hábákúkù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn jẹ́ ènìyàn ti a bẹ̀rù, tí a sì páyà,ìdájọ́ wọn, àti ọláńlá wọn,Yóò máa ti inú wọn jáde.

Hábákúkù 1

Hábákúkù 1:1-12