Hábákúkù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ó rúbọ sí àwọ̀n rẹ̀,ó sì ń ṣun tùràrí fún àwọ̀n-ńlá rẹ̀nítorí pẹ̀lú àwọ̀n rẹ̀ ni ó fí ń gbé ní ìgbádùntí ó sì ń gbádùn pẹ̀lú oúnjẹ tí ó bá wù ú.

Hábákúkù 1

Hábákúkù 1:10-17