Hábákúkù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sì tí sọ ènìyàn di bí ẹja inú òkun,bí àwọn ẹ̀dá inú òkun tí wọn ko ni alákòóso

Hábákúkù 1

Hábákúkù 1:9-17