Gálátíà 3:28-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Kò le sí Júù tàbí Gíríkì, ẹrú tàbí òmìnira, ọkùnrin tàbí ọbìnrin nítorí pé ọ̀kan ni nínú Kírísítì Jésù.

29. Bí ẹ̀yin bá sì jẹ́ ti Kírísítì, ǹjẹ́ ẹ̀yin ní irú-ọmọ Ábúráhámù, àti àrólé gẹ́gẹ́ bí ìlérí.

Gálátíà 3