Gálátíà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n a kò fi agbára mú Títù tí ó wà pẹ̀lú mi, ẹni tí í ṣe ara Gíríkì láti kọlà.

Gálátíà 2

Gálátíà 2:1-8