Fílípì 1:28-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. láìsí ìbẹ̀rẹ̀ àwọn tí ó dojúkọ yin lọ́nà kanna. Èyí sì jẹ́ àmì fún wọn pé a ó pa wọ́n run, a ó sì gbà yín là —èyí tí Ọlọ́run yí ó ṣe.

29. Nítorí a ti fi fún yín nítorí Kírísítì, kì í ṣe láti gbàgbọ́ nínú rẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí rẹ̀ pẹ̀lú.

30. Nípa níní ìjàkadì kan náà tí ẹ̀yin ti rí tí èmi là kọjá, ti ẹ sì gbọ́ nísinsinyìí pé mo sì wà nínú rẹ̀.

Fílípì 1