Fílímónì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣíbẹ̀ nítorí ìfẹ́ èmí kúkú bẹ̀ ọ́. Èmi gẹ́gẹ́ bí Pọ́ọ̀lù, arúgbó, àti nísinsìnyìí òǹdè Jésù Kírísítì.

Fílímónì 1

Fílímónì 1:5-15