Fílímónì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbẹ́kẹ̀lé ti mo ní pé ìwọ yóò gbọ́ràn, ni mo fi kọ ìwé yìí ránsẹ́ sí ọ. Mo mọ̀ dájú pé ìwọ yóò se ju bí mo ti béèrè lọ.

Fílímónì 1

Fílímónì 1:15-25