Fílímónì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bóyá ìdí rẹ̀ tí òun fi yẹra kúrò lọ́dọ̀ rẹ fún ìgbà díẹ̀ ni pé kí ìwọ kí ó lè gbà á padà sọ́dọ̀ títí láé;

Fílímónì 1

Fílímónì 1:7-21