Fílímónì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ìbá fẹ́ láti dá a dúró sọ́dọ̀ mi níhìn-ín, kí ó baà dípò rẹ láti máa ràn mí lọ́wọ́ nígbà tí mo wà nínú ìdè nítorí ìyìn rere

Fílímónì 1

Fílímónì 1:9-21