Ẹ́sítà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì bọ́ òrùka dídán an rẹ̀, èyí tí ó ti gbà lọ́wọ́ọ Hámánì ó sì fi fún Módékáì, Ẹ́sítà sì yàn án gẹ́gẹ́ bí olóórí ilée Hámánì.

Ẹ́sítà 8

Ẹ́sítà 8:1-4