Ẹ́sítà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

jẹ́ kí wọn kí ó mú aṣọ ọba èyí tí ọba ń wọ̀ àti ẹṣin tí ọba má a ń gùn, pẹ̀lú ọ̀kan lára adé ọba kí a fi dé e ní orí.

Ẹ́sítà 6

Ẹ́sítà 6:1-11