Ẹ́sítà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Módékáì sọ ohun gbogbo tí ó ṣẹlẹ̀ fún-un, papọ̀ pẹ̀lú iye owó tí Hámánì ti ṣe ipinnu láti san sínú àpò ìṣúra ọba fún ìparun àwọn Júù.

Ẹ́sítà 4

Ẹ́sítà 4:1-16