Ẹ́sítà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ó lọ sí ẹnu ọ̀nà ọba nìkan, nítorí kò sí ẹnìkan tí ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀ tì a gbà láàyè láti wọ ibẹ̀.

Ẹ́sítà 4

Ẹ́sítà 4:1-9