Ẹ́sítà 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kejìlá ọba Ṣérísésì, ní oṣù kìn-ín-ní, èyí ni oṣù nísánì, wọ́n da Púrì (èyí tí í ṣe, ìbò) ní iwájú Hámánì láti yan ọjọ́ kan àti oṣù, ìbò náà sì wáyé ní oṣù kejìlá, oṣù Ádárì.

Ẹ́sítà 3

Ẹ́sítà 3:1-15