Ẹ́sítà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni yóò ṣe lọ ṣíwájú ọba: ohunkóhun tí ó bá béèrè ni wọ́n fi fún-un láti inú ilé àwọn obìnrin lọ sí ààfin ọba.

Ẹ́sítà 2

Ẹ́sítà 2:6-21