Ẹ́sítà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ojoojúmọ́ ni Módékáì máa ń rìn ní iwájú ilé àwọn obìnrin láti wo bí Ẹ́sítà ṣe wà àti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí i.

Ẹ́sítà 2

Ẹ́sítà 2:7-21