Ẹ́sítà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe àfihàn púpọ̀ ọrọ̀ ìjọba rẹ̀ àti dídán àti ògo ọlá ńlá a rẹ̀ fún ọgọ́sàn-án ọjọ́ gbáko.

Ẹ́sítà 1

Ẹ́sítà 1:3-5