Ẹ́sítà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò ìgbà náà ọba Ṣérísésì ń ṣe ìjọba ní orí ìtẹ́ ẹ rẹ̀ ní ilé ìṣọ́ ti Ṣúsà,

Ẹ́sítà 1

Ẹ́sítà 1:1-10