Ẹ́sítà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mémúkánì sì dáhùn níwájú ọba àti àwọn ọlọ́lá pé, “Ayaba Fásítì ti ṣe búburú, kì í ṣe sí ọba nìkan Ṣùgbọ́n sí gbogbo àwọn ọlọ́lá àti àwọn ènìyàn tí ó wà ní gbogbo agbégbé ilẹ̀ ọba Ṣérísésì.

Ẹ́sítà 1

Ẹ́sítà 1:12-22