Ẹ́sírà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nínú àwọn ọmọ Ádóníkámù, àwọn ti ó gbẹ̀yìn, tì orùkọ wọn ń jẹ̀ Élífélétì, Jéúélì àti Ṣémáyà, àti ọgọ́ta (60) ọkúnrin pẹ̀lú wọn;

Ẹ́sírà 8

Ẹ́sírà 8:3-18