Ẹ́sírà 7:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ní àkókò ìjọba ọba Aritaṣéṣéṣì ní Páṣíà, Ẹ́sírà ọmọ Ṣéráíyà, ọmọ Ásáríyà, ọmọ Hílíkíyà,

2. Ọmọ Ṣálúmù, ọmọ Ṣádókù, ọmọ Áhítúbì,

3. ọmọ Ámáríyà, ọmọ Ásáríyà, ọmọ Méráíótù,

4. ọmọ Ṣéráháyà, ọmọ Húsì, ọmọ Búkì,

Ẹ́sírà 7