Ẹ́sírà 6:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A parí ilé Olúwa ní ọjọ́ kẹta, oṣù Ádárì (oṣù kejì) ní ọdún kẹfà ti ìjọba ọba Dáríúsì.

Ẹ́sírà 6

Ẹ́sírà 6:7-22