Ẹ́sírà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A bi àwọn àgbààgbà, a sì fi ọ̀rọ̀ wá wọn lẹ́nu wò pé, “Ta ni ó fún un yín ní àṣẹ láti tún ilé Olúwa yìí kọ́ àti láti tún odi rẹ̀ mọ?”

Ẹ́sírà 5

Ẹ́sírà 5:7-12