Ẹ́sírà 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì tún béèrè pé, “Kí ni orúkọ àwọn ọkùnrin tí ó ń kọ́ ilé yìí?”

Ẹ́sírà 5

Ẹ́sírà 5:1-5