Ẹ́sírà 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nítorí tí àwọn baba wa mú Ọlọ́run ọ̀run bínú, ó fi wọ́n lé Nebukadinésárì ti Kálídéà, ọba Bábílónì lọ́wọ́, ẹni tí ó run tẹ́ḿpìlì Olúwa yìí tí ó sì kó àwọn ènìyàn náà padà sí Bábílónì.

Ẹ́sírà 5

Ẹ́sírà 5:9-17