Ẹ́sírà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Ṣérísésì wọ̀n fi ẹ̀sùn kan àwọn ènìyàn Júdà àti Jérúsálẹ́mù.

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:1-7