Ẹ́sírà 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ṣọ́ra kí ẹ má ṣe àìkọbi-ara sí ọ̀rọ̀ yìí. Èéṣe tí ìbàjẹ́ yóò fi pọ̀ sí i, sí ìpalára àwọn ọba?

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:13-23