Ẹ́sírà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n wá sí ọ̀dọ̀ Ṣérúbábélì àti sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí àwọn ìdílé, wọ́n sì wí pé, “Jẹ́ kí a bá a yín kọ́ nítorí pé, bí i ti yín, a ń wá Ọlọ́run yín, a sì ti ń rúbọ sí i láti ìgbà Ésáríhádónì ọba Ásíríà, tí ó mú wa wá síbi yìí.”

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:1-9