Ẹ́sírà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pẹ̀lú àwọn ènìyàn mìíràn tí ẹni ọlá àti ẹni ọ̀wọ̀ Áṣúríbánípálì lé jáde tí ó sì tẹ̀ wọ́n dó sí ìlú Samáríà àti níbòmíràn ní agbègbè e Yúfúrátè.

Ẹ́sírà 4

Ẹ́sírà 4:7-19