Ẹ́sírà 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹni tí ó le mọ́ ìyàtọ̀ láàárin igbe ayọ̀ àti ẹkún, nítorí tí ariwo àwọn ènìyàn náà pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́. Wọ́n sì gbọ́ igbe náà ní ọ̀nà jínjìn réré.

Ẹ́sírà 3

Ẹ́sírà 3:5-13