Ẹ́sírà 10:41-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

41. Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà,

42. Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù.

43. Nínú àwọn ìran Nébò:Jérélì, Mátítaíyà, Ṣábádì, Ṣábínà, Jádáì, Jóélì àti Bénáíáyà.

44. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipaṣẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.

Ẹ́sírà 10