37. Mátítamáyà, Mátíténáì àti Jáásù.
38. Nínú àwọn ìran Bínúì:Ṣíméhì,
39. Ṣélémíáyà, Nátanì, Ádáyà,
40. Mákánádébáì, Ṣásíáì, Ṣáráì,
41. Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà,
42. Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù.
43. Nínú àwọn ìran Nébò:Jérélì, Mátítaíyà, Ṣábádì, Ṣábínà, Jádáì, Jóélì àti Bénáíáyà.