Ẹ́sírà 10:32-37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

32. Bénjámínì, Málílúkì àti Ṣémáríà.

33. Nínú àwọn ìran Hásíúmù:Mátíténáì, Mátítatítayà, Ṣábádì, Élífélétì, Jérémáì, Mánásè àti Ṣíméhì.

34. Nínú àwọn ìran Bánì:Máádáì, Ámírámù, Úélì,

35. Bénáíáyà, Bédéíáyà, Kélúhì,

36. Fáníyà, Mérémótì, Élíásíbù,

37. Mátítamáyà, Mátíténáì àti Jáásù.

Ẹ́sírà 10