Ẹ́sírà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára ìran àwọn àlùfáà àwọn wọ̀nyí fẹ́ àwọn obìnrin àjèjì:Nínú ìran Jésíúà ọmọ Jósádákì, àti àwọn arákùnrin rẹ: Mááséáyà, Élíásérì, Járíbù àti Gédáláyà.

Ẹ́sírà 10

Ẹ́sírà 10:16-26