Ẹ́sírà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Sáírúsì ọba Páṣíà wí pé: Olúwa, Ọlọ́run ọ̀run, ti fún mi ní gbogbo ìjọba ayé. Ó sì ti yàn mí láti kọ́ tẹ́ḿpìlì Olúwa fún un ní Jérúsálẹ́mù tí ó wà ní Júdà.

Ẹ́sírà 1

Ẹ́sírà 1:1-11