Ẹkún Jeremáyà 5:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Mú wa padà sí ọ̀dọ̀ rẹ, Olúwa, kí àwa kí ó le padà;mú ọjọ́ wa di tuntun bí ìgbà a nì

22. Àyàfi tí o bá ti kọ̀ wá sílẹ̀ pátápátátí ìbínú rẹ sí wa sì kọjá ìwọ̀n.

Ẹkún Jeremáyà 5