Ẹkún Jeremáyà 4:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ẹ yọ̀ kí inú yín sì dùn, ẹ̀yin ọmọbìnrin Édómù,ẹ̀yin tó ń gbé ní ilẹ̀ Húsì.Ṣùgbọ́n, a ó gbé aago náà kọjá sọ́dọ̀ rẹ pẹ̀lú;ìwọ yóò yó bí ọ̀mùtí, ìwọ yóò sì rìn ní ìhòòhò.

22. Ìwọ ọmọbìnrin Síónì, ìjìyà rẹ yóò dópin;kò ní mú ìgbékùn rẹ pẹ́ mọ́.Ṣùgbọ́n, ìwọ ọmọbìnrin Édómù, yóò jẹ ẹ̀sẹ̀ rẹ níyàyóò sì fi àìṣedédé rẹ hàn kedere.

Ẹkún Jeremáyà 4