Ẹkún Jeremáyà 3:56-61 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

56. Ìwọ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi: “Má ṣe di etí rẹsí igbe ẹ̀bẹ̀ mi fún ìtura.”

57. O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́,o sì wí pé, “Má se bẹ̀rù.”

58. Olúwa, ìwọ gba ẹjọ́ mi rò,o ra ẹ̀mí mi padà.

59. O ti rí i, Olúwa, búburú tí a ṣe sí miGbé ẹjọ́ mi ró!

60. Ìwọ ti rí ọ̀gbun ẹ̀san wọn,gbogbo ìmọ̀ wọn sí mi.

61. Olúwa ìwọ ti gbọ́ ẹ̀gàn wọnàti ìmọ̀ búburú wọn sí mi—

Ẹkún Jeremáyà 3