Ékísódù 8:30-32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Nígbà náà ni Mósè kúrò ni ọ̀dọ̀ Fáráò, ó sì gbàdúrà sí Olúwa;

31. Olúwa sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Mósè ti béèrè: Àwọn esinsin kúrò lára Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ àti lára àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú, esinsin kan kò sì sẹ́kù.

32. Ṣùgbọ́n ni àkókò yìí náà, Fáráò sé ọkàn rẹ le kò sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn ó lọ.

Ékísódù 8