Ékísódù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò dáhùn wí pé, “Ta ni Olúwa, tí èmi yóò fi gbọ́ràn sí i lẹ́nu, tí èmi yóò fi jẹ́ kí Ísírẹ́lì ó lọ? Èmi kò mọ Olúwa, èmi kò sì ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì ó lọ.”

Ékísódù 5

Ékísódù 5:1-3