Ékísódù 36:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì wí pé, “Àwọn ènìyàn mú púpọ̀ wá fún síṣe iṣẹ́ náà ju bi Olúwa ti pa á láṣẹ láti ṣe lọ.”

Ékísódù 36

Ékísódù 36:2-15