“Ìwọ yóò sì fi ọ̀gbọ̀ dáradára hun ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀, ìwọ yóò sì fi ọ̀gbọ̀ dáradára ṣe fìlà. Iwọ yóò sì fi ṣẹ́ abẹ́rẹ́ ṣe ọ̀já àmùrè.