Ékísódù 24:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà náà ni Olúwa sọ fún Mósè pé, “Gòkè tọ Olúwa wá, ìwọ àti Árónì, Nádábú àti Ábíhù àti àádọ́rin (70) àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì. Ẹ̀yin kì ó sìn ni òkèèrè réré.

Ékísódù 24

Ékísódù 24:1-7