Ékísódù 20:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa sì sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí pé:

2. “Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, ẹni tí ó mú un yín jáde ni ilẹ̀ Éjíbítì, jáde ni oko ẹrú.

3. “Ìwọ kò gbọdọ̀ ní Ọlọ́run mìíràn pẹ̀lú mi.

Ékísódù 20