Ékísódù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wo ìhín, ó wo ọ̀hún, nígbà tí kò rí ẹnìkankan, ni ó bá pa ará Éjíbítì náà, ó sì bò ó mọ́ inú iyanrìn.

Ékísódù 2

Ékísódù 2:5-15