Éfésù 4:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má sì ṣe mú Ẹ̀mí Mímọ́ Ọlọ́run bínú, ẹni tí a fi ṣe èdìdì yín dé ọjọ́ ìdáǹdè.

Éfésù 4

Éfésù 4:22-32